Our Services



News From The BBC

A Yoruba Perspective


Mi ò jẹ̀bi ẹ̀sùn fífi owó N18.96bn tẹ N684m – Emefiele
Emefiele yoo ma sọrọ niwaju Onidajọ Maryann Anenih sugbọn lasiko yii, yoo ma jẹjọ lori ẹsun ọdaran mii lori pe o tẹ owo sita lọna aitọ, to si gba owo sita lọna ti ko ba ofin mu .

"Àlàyé rèé lórí ìdí tí mo ṣe dáná sun Mọ́ṣáláṣí, tí èmi àti èèyàn 24 míì sì fara pa"
Agbẹnusọ fun ileesẹ ọlọpaa nipinlẹ Kano salaye pe ọmọkunrin naa ni oun fẹ gbẹsan lara awọn ẹbi oun to n ba oun ṣe ajọpin ibusun ni.

Báwo ló ṣe yẹ kí afurasí kan hùwà lásìkò tí Ọlọ́pàá bá fẹ́ mú u?
BBC Yoruba kan si awọn agbofinro ati agbẹjọrọ lati ṣalaye ohun ti ofin sọ nipa titako igbesẹ ọlọpaa lati mu ni bii afurasi.

Tinubu fòǹtẹ̀ lu lílá ọ̀nà túntun láti Iseyin sí Okeho lọ Iganna l‘Oyo
Agbẹnusọ Aarẹ, Bayo Onanuga, lo fi ikede naa sita loju opo X rẹ lẹyin ipade naa pe lara awọn iṣẹ ọhun ni fifi ontẹ lu iwe irinna laarin ọjọ meji pere.

Kí ló dé tí àjọ Ayánilówó Àgbáyé (IMF) ń tojú bọ ọrọ̀ ajé Naijiria?
Apẹẹrẹ bi wọn ṣe n da si ọrọ Naijiria ni imọran ti wọn gba Naijiria laipẹ yii, pe kijọba yee sanwo iranwọ lori ina, eyi ti ijọba si gba.

Ìlú kan rèé tí wọ́n ti máa ń rí àwọn èèyàn tó bọ́ lọ́wọ́ ìkọlù ààrá mọ́lẹ̀ láàyè
Ní ọjọ́ Àìkú ni ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé ní agbègbè Melka Bello, ìlú kan tó wà ní kìlómítà 450 sí Addis Ababa tó jẹ́ olú ìlú orílẹ̀ èdè Ethiopia.

Àwọn ọmọ ìta wọ̀já ìjà l‘Osogbo, ẹ̀mí alágbe kan bá ìṣẹ̀lẹ̀ náà lọ
Aṣita ibọn awọn janduku ti sọ ọkunrin alagbe kan di ero ọrun ojiji bayii, laduugbo Gbaemu,Oṣogbo, nipinlẹ Ọṣun.

Mọ̀ nípa abẹ́rẹ́ tó ń dá ebi dúró, mú àdínkù bá ara sísán, tó sì ń dènà àìsàn ọkàn
Ọjọgbọn John Deanfield lo lewaju awọn oniwadii to se abẹrẹ naa sọ pe abẹrẹ yii le tun ni ipa nla lati mu ki ifunpa ati itọ suga eeyan wa silẹ, ti yoo si tun ṣe anfani nla fun ọkan.

Báwo ló ṣe yẹ kí afurasí kan hùwà lásìkò tí Ọlọ́pàá bá fẹ́ mú u?
BBC Yoruba kan si awọn agbofinro ati agbẹjọrọ lati ṣalaye ohun ti ofin sọ nipa titako igbesẹ ọlọpaa lati mu ni bii afurasi.

Olórí ilé aṣòfin fẹ́ fi obìnrin 100 lọ́kọ, Mínísítà fọ́rọ̀ obìnrin pe ẹjọ́
minisita fun ọrọ obinrin Naijiria ni se lo yẹ ki Olori ile asofin ni Kogi ro awọn ọmọbinrin naa lagbara dipo ko fi wọn lọ́kọ.

Ìjọba Nàìjíríà wọ́gilé owó orí ìdá 0.5% tó kéde fún àbò lọ́wọ́ jìbìtì orí ayélujára
Ìjọba Nàìjíríà wọ́gilé Laipẹ yii ni banki apapọ Naijiria kede owó orí ìdá 0.5% fún àbò lọ́wọ́ jìbìtì orí ayélujára to pe ni Cybersecurity levy.

Pátákó ìpolówó ọjà wó pa èèyàn mẹ́rìnlá tó sá sábẹ́ rẹ̀ lásìkò ìjì òjò líle, ọ̀pọ̀ míì farapa, mọ́tò bàjẹ́
Awọn oṣiṣẹ pajawiri ṣalaye pe awọn eeyan kan ṣi wa labẹ patako to da wo naa, bẹẹ ni iṣẹ si n lọ lọwọ lati yọ wọn.

Wo igi mẹ́ta tí wọn ń bọ ní Ibeju-Lekki, ó máa ya lulẹ̀ bí Ọba bá wàjà, ẹni tó bá fọwọ́ kàn -àn, yóò gbẹ, àdúrà tàbí èpè níbẹ̀ yóò wá sí ìmúṣẹ
BBC Yorùbá dé ìlú Ibeju Lekki ní ìpínlẹ̀ Eko níbi tí wọn ti ń bọ igi mẹ́ta tí ọjọ́ orí wọn lé ní igba ọdún. A sì gbọ́ nípa àwọn èèwọ̀ àti àǹfààní àwọn igi náà.

Stevie Wonder di ọmọ orìlẹ̀èdè Ghana
Ọmọ orilẹede Amẹrika ni Stevie Wonder ki ijọba Ghana to fun un ni iwe aṣẹ ọmọ onilu.

'Ojoojúmọ́ ni wọ́n ń ja àwọn èèyàn lólè tàbí pa wọn, mò ń gbàdúrà lọ́sàn-án àti lóru fún ààbò'
Bí ìwà ìpànìyàn ṣe ń lékún ní orílẹ̀ èdè South Africa láti bíi ogún ọdún báyìí, BBC Africa Eye bá àwọn ìlú tí wọ́n ń jà fúnra wọn sọ̀rọ̀.

Akẹ́kọ̀ọ́ táwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ fìyà jẹ l'Abuja gbé ilé ẹ̀kọ́ rẹ̀ relé ẹjọ́, bèèrè fún N500m owó gbà má bìnú
Ileeṣẹ amofin to n ṣoju Namitra Bwala salaye pe ẹjọ ti akẹkọọbinrin naa pe yoo jẹ ki opin de ba iru iwa ifiyajeni yii lọgba ile ẹkọ.

Àwọn obìnrin fọ́nmú bí Alfa obìnrin, Kafilat Kaola ṣe wọ́ Saheed Shittu lọ sílé ẹjọ lórí ẹ̀sùn àgbèrè àti ríra ọmọ
Saheed Shittu ni Alhaja Kafilat Kaola pe lẹjọ fun ẹsun ibanilorukọjẹ, ti Ileẹjọ si ni ki olujẹjọ wa dahun awọn ibeere lori ẹsun naa.

Àwọn agbébọn pa ọ̀gá wọ́dà méjì, ẹlẹ́wọ̀n sá lọ
Ààrẹ Macron ní ìgbésẹ̀ tí ń lọ láti ṣàwárí àwọn agbebọn to ṣọṣẹ́ náà.

Adeleke, máṣe dáwọ́ ijó jíjó dúró àmọ́ mú ìṣèjọba rere ní pàtàkì l‘Osun - Obasanjo
Olusegun Obasanjo gba Ademola nimọran pe ko sa gbogbo agbara rẹ lati mu igbesi aye irọrun ba awọn olugbe ipinlẹ Ọṣun.

Àbúrò mẹ́wàá ni mo pàdánù nínú ìkọlù Israel sí gúúsù Gaza
Ọsibitu Al Aqsa to wa ni Deir al-Balah, ti sọ pe ko din ni eeyan mọkanlelogun to ku ninu ikọlu to waye laarin gbungbun Gaza.

Wo àwòrán Ọmọọba Harry àti Ìyàwó rẹ̀ nígbà tí wọ́n dé sí Naijiria
Ọmọọba ile Gẹẹsi, Ọmọọba Harry ati Iyawo rẹ Meghan ṣe abẹwo si orilẹede Naijiria.

Èèyàn 1,097 làwọn agbébọn ṣekúpa lóṣù kẹrin ní Nàìjíríà – Àbọ̀ ìwádìí
Amọṣa o, abọ iwadii naa fi kun un pe ọwọja ikọlu awọn agbebọn atawọn ajinigbe pawo lawọn ileto kaakiri ti walẹ.

"Mo máa ń ṣọ́ra gan an:" Wo bí àwọn akọ̀ròyìn BBC tó ń ṣàtìpó nílẹ̀ òkèèrè ṣe ń pọ̀ si
Ọpọ akọroyin BBC lo kuro ni Afghanistan nigba ti awọn Taliban gbjoba lọdun 2021. Awọn oṣiṣẹ to jẹ obinrin ko le ṣiṣẹ mọ, nigba ti wọn n dunkoko mawọn ọkunrin.

Ṣé lóòótọ́ ni àwọn kan n fi ìforúkọsílẹ̀ NIMC lu àwọn èèyàn ní jìbìtì?
Eyii ni ijọba apapọ lohun ṣe lati dẹkun iwa ijinigbe, jibiti ati oniruuru iwa ọdaran kaakiri.

Àwọn nǹkan mẹ́jọ tó yẹ kó o mọ̀ nípa Dorcas Adeyinka tí ọlọ́pàá kéde pé àwọn ń wá
Ileeṣẹ ọlọpaa ṣapejuwe Adeyinka gẹgẹ bi akọroyin ori ayelujara lati ilu Ekiti ati Ibadan, tiu wọn si tun juwe rẹ bi Ọlọrun ṣe ṣẹda rẹ.

Oluwo fún ìyàwó Ọmọọba ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Meghan ni orúkọ Yorùbá
Eyi waye lasiko ti wọn pade nibi ayẹyẹ ti ileeṣẹ ologun gbe kalẹ lati yẹ Duke ati Duchess si ni ile itura Delborough niluu Eko.

Mọ̀ si nípa ọkọ̀ tó ń lo afẹ́fẹ́ gáàsì tí ìjọba kó wọlé láti rọ́pò ọkọ̀ tó ń lo epo bẹntiró
BBC Yoruba ṣe ẹkunrẹrẹ iwadii nipa awọn ọkọ to n lo afẹfẹ gaasi pẹlu iyatọ to wa laarin rẹ ati awọn ọkọ to n lo epo bẹntiroolu.

Ọwọ́ tẹ 32 awakùsà lọ́nà àìtọ́ l'Oyo
Olori ikọ Operation Burst nipinlẹ Oyo, Col James Oladipo Ajibola lo kede eyii fun awọn akọroyin lẹyin ipade to ṣe pẹlu igbakeji Gomina ipinlẹ Oyo.

'Irọ́ ni mo pa pé Ọọni Ile-Ife ni bàbá mi àmọ́ ìdí tí mo fi parọ́ rèé'
Ninu fọnran to ti n bẹbẹ ọhun lo ti sọ pe ala toun la lọdun diẹ sẹyin wi pe kabiyesi fun oun ni ilẹkẹ, toun si gbiyanju lati ri kabiyesi, ṣugbọn to ja si pabo lo jẹ koun sọ pe kabiyesi ni baba oun.

Femi Adebayo, Layi Wasabi, Kehinde Bankole àtàwọn míì gba àmì ẹ̀yẹ AMVCA 2024
Ami ẹyẹ Africa Magic Viewers’Choice Award lo jẹ ami ẹyẹ kan to lamilaka fun awọn oṣere nilẹ Africa.

Ìjọba Eko dáwọn ọmọ Osun tó ń gbé Eko padà sílé, gómìnà Adelele fọnmú
BBC News Yoruba ba awọn eeyan ti ọrọ kan lori iṣẹlẹ naa sọrọ.

Ọjọ́ wo gan ní àyájọ́ obìnrin lágbàyéé Mothers Day, kí ló dé tí wọn fí n ṣé ajọyọ rẹ̀ lọ̀pọ̀ ìgbà?
Ayajọ ọjọ iranti awọn obinrin ni wọn ya sọtọ lati fiṣe ayẹsi pataki ati ipa tawọn iya n ko lagbaye.

Ṣé lóòtọ́ọ́ ni ìjàmbá ọkọ̀ ṣẹlẹ̀ sí Tijani Babangida agbábọ́ọ̀lù Náíjíríà tẹ́lẹ̀ rí?
Garba lawal to jẹ akẹgbẹ Babangida ninu ikọ agbabọọlu Super Eagles fidi iṣẹlẹ ọhun mulẹ fun BBC pe lootọọ ni iṣẹlẹ naa waye.

Ilé aṣòfin àgbà l'Abuja buwọ́lu ìdájọ́ ikú fáwọn tó ń gbé oògùn olóró
Sẹnẹtọ Peter Nwebonyi lo daba wi pe ki ile aṣofin fi idajọ iku rọpo ẹwọn gbere to jẹ ijiya fawọn ti wọn ba gbamu fun kata kara oogun oloro.

Aráàlú ṣèwọ́de ìfẹ̀hónúhàn torí ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ ní Benin Republic
BBC kọwọrin pẹlu awọn araalu ati osisẹ ijọba lasiko ti wọn ṣe ifẹhonuhan naa

Kí ló dé tí Garri gbé owó lórí lọ́jà? -
Ileeṣẹ BBC tẹ ọkọ leti lọ oko Garri lati lọ ba awọn agbẹ sọrọ paapa awọn agbẹ to mọ nipa ẹgẹ.

Local Housing

This is one of the main issues facing local people. The inadequacy of social housing stock continues to be the main concerns of local people. And it is getting worst.

Read More

Drugs And Illegal Substances

Taking illegal drug is always fraught with danger. You don't need me to tell you that - your grand mother will say the same. The high very often tend to perpetual low that you will never get out from. Get advise now before it is too late

Read More

Knife Attacks

Who goes around with a knive as weapon of protection is deluded. It will inevitably be your comeuppance. Just in case you do not understand, it will kill you. There is no justification for carrying a knive excerpt when you are foraging in the jungle.

Read More

Gang Culture

We were all young once - doing things adults will frown upon. This was at school or in the play grounds. But as we grew up, people we wanted to associate with start to shrink in numbers as our brain matured correspondingly and as a result doing the right thing. Pick your friends judiciously.

Read More

Local Parks

From a personal experience - the local park is a refuge for meditation,physical exploration and mental rejuvination. Just go for a slow run and see how you feel afterwards. Physical and mentally rewarding. Don't just take my words for it - it is a scientific fact. Please do try it.

Read More

24/7 Support

We are your one stop local solution advocate. Dont't carry all that weight on your own we are here to not only relief some of it, but to help you get back to you again.

Read More
Established since 2000

We Are Ready To Assist